iye iye
olori aye oooo mo ki ooo
iye iye
aah e Jesu seun
o f'ami ororo yan mi
oni ma foya/2x
nwo korin ogo re titi lailai/4x
verse 2: elerun niyin
oba awi maaye 'hun
gbongbo 'dile jese aterere kari aye
eyin lope ye, eyin niyin ye oo
dansaki re olu olorun oba mi mokio oo
aah ee...
verse 3: mo wo kari aye boya emi o ri oba bi re o, laye at'orun koma seni keni bi re oo baba, oba ti ki'n doju tini asoro matase, emi o gbeoga nko korin ogo re titi lailailailailailailai
aaah ee
bridge: ooooolori aye oooo, oba ti n fi imole s'aso 'bora, kaabiesi
call: Jesu seun
resp. Jesu seun/3x
call: olugbala seun
resp: Jesu seun
call: eledami seun
resp. iba feledumare oba
call: Olorun mi seun seun oo
resp. iba feledumare oba
call: eledumare oseun
resp. iba feledumare oba
call: olorun mi seun seun ooo
resp. iba feledumare oba
Jesu seun iba f'eledumare oba...